Native Bible

Psalms 102:6 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Èmi dàbí ẹyẹ igún ní ijù: èmi dàbí òwìwí ibi ahoro.

Psalms 102:6 in English

Psalms 102:6 · Berean Standard Bible

I am like a desert owl, like an owl among the ruins.

Context

4Àyà mi lù, ó sì rọ bí i koríko; mo gbàgbé láti jẹ oúnjẹ mi. 5Nítorí ohùn ìkérora mi, egungun mi lẹ̀ mọ́ ẹran-ara mi. 6Èmi dàbí ẹyẹ igún ní ijù: èmi dàbí òwìwí ibi ahoro. 7Èmi dìde; èmi dàbí ẹyẹ lórí ilé. 8Ní ọjọ́ gbogbo, àwọn ọ̀tá ológoṣẹ́ mi ń gàn mí; àwọn tí ń ṣe ìkanra sí mi ń fi orúkọ mi bú.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.