Saamu 102:8
Psalms 102:8 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ní ọjọ́ gbogbo, àwọn ọ̀tá ológoṣẹ́ mi ń gàn mí; àwọn tí ń ṣe ìkanra sí mi ń fi orúkọ mi bú.
Psalms 102:8 in English
Psalms 102:8 · Berean Standard Bible
All day long my enemies taunt me; they ridicule me and curse me.
Context
6Èmi dàbí ẹyẹ igún ní ijù:
èmi dàbí òwìwí ibi ahoro. 7Èmi dìde; èmi dàbí ẹyẹ lórí ilé. 8Ní ọjọ́ gbogbo, àwọn ọ̀tá ológoṣẹ́ mi ń gàn mí;
àwọn tí ń ṣe ìkanra sí mi ń fi orúkọ mi bú. 9Èmi jẹ eérú gẹ́gẹ́ bí oúnjẹ mi, èmi sì da ohun mímu mi pọ̀ pẹ̀lú omijé. 10Nítorí ìbínú ríru rẹ, nítorí ìwọ ti gbé mi sókè, ìwọ sì gbé mi ṣánlẹ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.