Saamu 102:7
Psalms 102:7 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Èmi dìde; èmi dàbí ẹyẹ lórí ilé.
Psalms 102:7 in English
Psalms 102:7 · Berean Standard Bible
I lie awake; I am like a lone bird on a housetop.
Context
5Nítorí ohùn ìkérora mi,
egungun mi lẹ̀ mọ́ ẹran-ara mi. 6Èmi dàbí ẹyẹ igún ní ijù:
èmi dàbí òwìwí ibi ahoro. 7Èmi dìde; èmi dàbí ẹyẹ lórí ilé. 8Ní ọjọ́ gbogbo, àwọn ọ̀tá ológoṣẹ́ mi ń gàn mí;
àwọn tí ń ṣe ìkanra sí mi ń fi orúkọ mi bú. 9Èmi jẹ eérú gẹ́gẹ́ bí oúnjẹ mi, èmi sì da ohun mímu mi pọ̀ pẹ̀lú omijé.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.