Native Bible

Numbers 32:35 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

pẹ̀lú Atrotu Ṣofani, Jaseri, àti Jogbeha,

Numbers 32:35 in English

Numbers 32:35 · Berean Standard Bible

Atroth-shophan, Jazer, Jogbehah,

Context

33Nígbà náà Mose fún àwọn ọmọ Gadi àti àwọn ọmọ Reubeni àti ààbọ̀ ẹ̀yà Manase ọmọ Josẹfu ní ilẹ̀ ọba Sihoni ọba àwọn ọmọ Amori àti ilẹ̀ ọba Ogu ọba Baṣani ní gbogbo ilẹ̀ náà pẹ̀lú ìlú rẹ̀ àti agbègbè tí ó yí i ka. 34Àwọn ará Gadi wọ́n kọ́ Diboni, Atarotu, Aroeri; 35pẹ̀lú Atrotu Ṣofani, Jaseri, àti Jogbeha, 36pẹ̀lú Beti-Nimra, àti Beti-Harani ìlú olódi, àti agbo fún àgùntàn. 37Àwọn ọmọ Reubeni sì kọ́ Heṣboni, Eleale, Kiriataimu,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.