Native Bible

Numbers 32:34 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ará Gadi wọ́n kọ́ Diboni, Atarotu, Aroeri;

Numbers 32:34 in English

Numbers 32:34 · Berean Standard Bible

And the Gadites built up Dibon, Ataroth, Aroer,

Context

32A máa rékọjá níwájú Olúwa lọ sí Kenaani pẹ̀lú ìhámọ́ra, ṣùgbọ́n ẹrù tí a jogún yóò wà ní ẹ̀bá Jordani.” 33Nígbà náà Mose fún àwọn ọmọ Gadi àti àwọn ọmọ Reubeni àti ààbọ̀ ẹ̀yà Manase ọmọ Josẹfu ní ilẹ̀ ọba Sihoni ọba àwọn ọmọ Amori àti ilẹ̀ ọba Ogu ọba Baṣani ní gbogbo ilẹ̀ náà pẹ̀lú ìlú rẹ̀ àti agbègbè tí ó yí i ka. 34Àwọn ará Gadi wọ́n kọ́ Diboni, Atarotu, Aroeri; 35pẹ̀lú Atrotu Ṣofani, Jaseri, àti Jogbeha, 36pẹ̀lú Beti-Nimra, àti Beti-Harani ìlú olódi, àti agbo fún àgùntàn.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.