Numeri 32:36
Numbers 32:36 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
pẹ̀lú Beti-Nimra, àti Beti-Harani ìlú olódi, àti agbo fún àgùntàn.
Numbers 32:36 in English
Numbers 32:36 · Berean Standard Bible
Beth-nimrah, and Beth-haran as fortified cities, and they built folds for their flocks.
Context
34Àwọn ará Gadi wọ́n kọ́ Diboni, Atarotu, Aroeri; 35pẹ̀lú Atrotu Ṣofani, Jaseri, àti Jogbeha, 36pẹ̀lú Beti-Nimra, àti Beti-Harani ìlú olódi, àti agbo fún àgùntàn. 37Àwọn ọmọ Reubeni sì kọ́ Heṣboni, Eleale, Kiriataimu, 38pẹ̀lú Nebo pẹ̀lú Baali-Meoni (wọ́n pàrọ̀ orúkọ wọn) àti Sibma. Wọ́n sì sọ ìlú tí wọ́n tún kọ́ ní orúkọ mìíràn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.