Numeri 32:37
Numbers 32:37 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ọmọ Reubeni sì kọ́ Heṣboni, Eleale, Kiriataimu,
Numbers 32:37 in English
Numbers 32:37 · Berean Standard Bible
The Reubenites built up Heshbon, Elealeh, Kiriathaim,
Context
35pẹ̀lú Atrotu Ṣofani, Jaseri, àti Jogbeha, 36pẹ̀lú Beti-Nimra, àti Beti-Harani ìlú olódi, àti agbo fún àgùntàn. 37Àwọn ọmọ Reubeni sì kọ́ Heṣboni, Eleale, Kiriataimu, 38pẹ̀lú Nebo pẹ̀lú Baali-Meoni (wọ́n pàrọ̀ orúkọ wọn) àti Sibma. Wọ́n sì sọ ìlú tí wọ́n tún kọ́ ní orúkọ mìíràn. 39Àwọn ọmọ Makiri ọmọ Manase lọ sí Gileadi, wọ́n sì lé àwọn ọmọ Amori tí ó wà níbẹ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.