Native Bible

Numbers 13:15 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

láti inú ẹ̀yà Gadi, Geueli ọmọ Maki.

Numbers 13:15 in English

Numbers 13:15 · Berean Standard Bible

and from the tribe of Gad, Geuel son of Machi.

Context

13láti inú ẹ̀yà Aṣeri, Seturu ọmọ Mikaeli. 14láti inú ẹ̀yà Naftali, Nabi ọmọ Fofsi; 15láti inú ẹ̀yà Gadi, Geueli ọmọ Maki. 16Wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ènìyàn tí Mose rán láti lọ yẹ ilẹ̀ náà wò. (Hosea ọmọ Nuni ni Mose sọ ní Joṣua.) 17Nígbà tí Mose rán wọn lọ láti yẹ ilẹ̀ Kenaani wò, ó sọ fún wọn pé, “Ẹ gba ọ̀nà gúúsù lọ títí dé àwọn ìlú olókè.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.