Native Bible

Numbers 13:14 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

láti inú ẹ̀yà Naftali, Nabi ọmọ Fofsi;

Numbers 13:14 in English

Numbers 13:14 · Berean Standard Bible

from the tribe of Naphtali, Nahbi son of Vophsi;

Context

12láti inú ẹ̀yà Dani, Ammieli ọmọ Gemalli; 13láti inú ẹ̀yà Aṣeri, Seturu ọmọ Mikaeli. 14láti inú ẹ̀yà Naftali, Nabi ọmọ Fofsi; 15láti inú ẹ̀yà Gadi, Geueli ọmọ Maki. 16Wọ̀nyí ni orúkọ àwọn ènìyàn tí Mose rán láti lọ yẹ ilẹ̀ náà wò. (Hosea ọmọ Nuni ni Mose sọ ní Joṣua.)

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.