Numeri 10:27
Numbers 10:27 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ahira ọmọ Enani ni ọ̀gágun ti ẹ̀yà Naftali.
Numbers 10:27 in English
Numbers 10:27 · Berean Standard Bible
and Ahira son of Enan was over the division of the tribe of Naphtali.
Context
25Lákòótan, àwọn ọmọ-ogun tó ń mójútó ẹ̀yìn ló tún kàn, àwọn ni ìpín ti ibùdó Dani lábẹ́ ọ̀págun wọn. Ahieseri ọmọ Ammiṣaddai ni ọ̀gágun wọn. 26Pagieli ọmọ Okanri ni ìpín ti ẹ̀yà Aṣeri, 27Ahira ọmọ Enani ni ọ̀gágun ti ẹ̀yà Naftali. 28Báyìí ni àwọn ọmọ Israẹli ṣe tò jáde gẹ́gẹ́ bí ogun nígbà tí wọ́n bẹ̀rẹ̀ ìrìnàjò wọn. 29Mose sì sọ fún Hobabu ọmọ Reueli ará Midiani tí í ṣe àna rẹ̀ pé, “A ń gbéra láti lọ sí ibi tí Olúwa sọ pé, ‘Èmi ó fi fún un yín.’ Bá wa lọ, àwa ó ṣe ọ́ dáradára nítorí pé Olúwa ti ṣèlérí ohun rere fún Israẹli.”
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.