Native Bible

Numbers 10:26 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Pagieli ọmọ Okanri ni ìpín ti ẹ̀yà Aṣeri,

Numbers 10:26 in English

Numbers 10:26 · Berean Standard Bible

Pagiel son of Ocran was over the division of the tribe of Asher,

Context

24Abidani ọmọ Gideoni ni ọ̀gágun ìpín ti ẹ̀yà Benjamini. 25Lákòótan, àwọn ọmọ-ogun tó ń mójútó ẹ̀yìn ló tún kàn, àwọn ni ìpín ti ibùdó Dani lábẹ́ ọ̀págun wọn. Ahieseri ọmọ Ammiṣaddai ni ọ̀gágun wọn. 26Pagieli ọmọ Okanri ni ìpín ti ẹ̀yà Aṣeri, 27Ahira ọmọ Enani ni ọ̀gágun ti ẹ̀yà Naftali. 28Báyìí ni àwọn ọmọ Israẹli ṣe tò jáde gẹ́gẹ́ bí ogun nígbà tí wọ́n bẹ̀rẹ̀ ìrìnàjò wọn.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.