Numeri 10:24
Numbers 10:24 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Abidani ọmọ Gideoni ni ọ̀gágun ìpín ti ẹ̀yà Benjamini.
Numbers 10:24 in English
Numbers 10:24 · Berean Standard Bible
and Abidan son of Gideoni was over the division of the tribe of Benjamin.
Context
22Àwọn ìpín tó wà ní ibùdó Efraimu ló tún kàn lábẹ́ ọ̀págun wọn. Eliṣama ọmọ Ammihudu ni ọ̀gágun wọn. 23Gamalieli ọmọ Pedasuri ni ọ̀gágun ìpín ti ẹ̀yà Manase. 24Abidani ọmọ Gideoni ni ọ̀gágun ìpín ti ẹ̀yà Benjamini. 25Lákòótan, àwọn ọmọ-ogun tó ń mójútó ẹ̀yìn ló tún kàn, àwọn ni ìpín ti ibùdó Dani lábẹ́ ọ̀págun wọn. Ahieseri ọmọ Ammiṣaddai ni ọ̀gágun wọn. 26Pagieli ọmọ Okanri ni ìpín ti ẹ̀yà Aṣeri,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.