Numeri 1:6
Numbers 1:6 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Láti ọ̀dọ̀ Simeoni, Ṣelumieli ọmọ Suriṣaddai.
Numbers 1:6 in English
Numbers 1:6 · Berean Standard Bible
from Simeon, Shelumiel son of Zurishaddai;
Context
4Kí ẹ mú ọkùnrin kọ̀ọ̀kan láti inú olúkúlùkù ẹ̀yà kí ó sì wá pẹ̀lú yín, kí olúkúlùkù jẹ́ olórí ilé àwọn baba rẹ̀. 5“Orúkọ àwọn ọkùnrin tí yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ nìyí:
“Láti ọ̀dọ̀ Reubeni, Elisuri ọmọ Ṣedeuri. 6Láti ọ̀dọ̀ Simeoni, Ṣelumieli ọmọ Suriṣaddai. 7Láti ọ̀dọ̀ Juda, Nahiṣoni ọmọ Amminadabu. 8Láti ọ̀dọ̀ Isakari, Netaneli ọmọ Suari.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.