Native Bible

Numbers 1:7 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Láti ọ̀dọ̀ Juda, Nahiṣoni ọmọ Amminadabu.

Numbers 1:7 in English

Numbers 1:7 · Berean Standard Bible

from Judah, Nahshon son of Amminadab;

Context

5“Orúkọ àwọn ọkùnrin tí yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ nìyí: “Láti ọ̀dọ̀ Reubeni, Elisuri ọmọ Ṣedeuri. 6Láti ọ̀dọ̀ Simeoni, Ṣelumieli ọmọ Suriṣaddai. 7Láti ọ̀dọ̀ Juda, Nahiṣoni ọmọ Amminadabu. 8Láti ọ̀dọ̀ Isakari, Netaneli ọmọ Suari. 9Láti ọ̀dọ̀ Sebuluni, Eliabu ọmọ Heloni.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.