Native Bible

Numbers 1:5 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

“Orúkọ àwọn ọkùnrin tí yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ nìyí: “Láti ọ̀dọ̀ Reubeni, Elisuri ọmọ Ṣedeuri.

Numbers 1:5 in English

Numbers 1:5 · Berean Standard Bible

These are the names of the men who are to assist you: From the tribe of Reuben, Elizur son of Shedeur;

Context

3Ìwọ àti Aaroni ni kí ẹ kà gbogbo ọmọkùnrin Israẹli gẹ́gẹ́ bí ìpín wọn láti ọmọ ogún ọdún sókè, àwọn tí ó tó lọ sójú ogun. 4Kí ẹ mú ọkùnrin kọ̀ọ̀kan láti inú olúkúlùkù ẹ̀yà kí ó sì wá pẹ̀lú yín, kí olúkúlùkù jẹ́ olórí ilé àwọn baba rẹ̀. 5“Orúkọ àwọn ọkùnrin tí yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ nìyí: “Láti ọ̀dọ̀ Reubeni, Elisuri ọmọ Ṣedeuri. 6Láti ọ̀dọ̀ Simeoni, Ṣelumieli ọmọ Suriṣaddai. 7Láti ọ̀dọ̀ Juda, Nahiṣoni ọmọ Amminadabu.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.