Native Bible

Numbers 1:8 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Láti ọ̀dọ̀ Isakari, Netaneli ọmọ Suari.

Numbers 1:8 in English

Numbers 1:8 · Berean Standard Bible

from Issachar, Nethanel son of Zuar;

Context

6Láti ọ̀dọ̀ Simeoni, Ṣelumieli ọmọ Suriṣaddai. 7Láti ọ̀dọ̀ Juda, Nahiṣoni ọmọ Amminadabu. 8Láti ọ̀dọ̀ Isakari, Netaneli ọmọ Suari. 9Láti ọ̀dọ̀ Sebuluni, Eliabu ọmọ Heloni. 10Láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Josẹfu: láti ọ̀dọ̀ Efraimu, Eliṣama ọmọ Ammihudu. Láti ọ̀dọ̀ Manase, Gamalieli ọmọ Pedasuri.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.