Native Bible

Numbers 1:10 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Josẹfu: láti ọ̀dọ̀ Efraimu, Eliṣama ọmọ Ammihudu. Láti ọ̀dọ̀ Manase, Gamalieli ọmọ Pedasuri.

Numbers 1:10 in English

Numbers 1:10 · Berean Standard Bible

from the sons of Joseph: from Ephraim, Elishama son of Ammihud, and from Manasseh, Gamaliel son of Pedahzur;

Context

8Láti ọ̀dọ̀ Isakari, Netaneli ọmọ Suari. 9Láti ọ̀dọ̀ Sebuluni, Eliabu ọmọ Heloni. 10Láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Josẹfu: láti ọ̀dọ̀ Efraimu, Eliṣama ọmọ Ammihudu. Láti ọ̀dọ̀ Manase, Gamalieli ọmọ Pedasuri. 11Láti ọ̀dọ̀ Benjamini, Abidani ọmọ Gideoni. 12Láti ọ̀dọ̀ Dani, Ahieseri ọmọ Ammiṣaddai.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.