Native Bible

Numbers 1:11 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Láti ọ̀dọ̀ Benjamini, Abidani ọmọ Gideoni.

Numbers 1:11 in English

Numbers 1:11 · Berean Standard Bible

from Benjamin, Abidan son of Gideoni;

Context

9Láti ọ̀dọ̀ Sebuluni, Eliabu ọmọ Heloni. 10Láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Josẹfu: láti ọ̀dọ̀ Efraimu, Eliṣama ọmọ Ammihudu. Láti ọ̀dọ̀ Manase, Gamalieli ọmọ Pedasuri. 11Láti ọ̀dọ̀ Benjamini, Abidani ọmọ Gideoni. 12Láti ọ̀dọ̀ Dani, Ahieseri ọmọ Ammiṣaddai. 13Láti ọ̀dọ̀ Aṣeri, Pagieli ọmọ Okanri.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.