Nehemiah 7:41
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Paṣuri jẹ́ ẹgbẹ̀fà ó lé mẹ́tàdínláàádọ́ta (1,247)
Nehemiah 7:41 in English
Nehemiah 7:41 · Berean Standard Bible
the descendants of Pashhur, 1,247;
Context
39Àwọn àlùfáà:
àwọn ọmọ
Jedaiah (láti ipasẹ̀ ìdílé Jeṣua) jẹ́ ogún dín lẹ́gbẹ̀rin ó dín méje (973) 40Immeri jẹ́ àádọ́ta lé lẹ́gbẹ̀rún ó lé méjì (1,052) 41Paṣuri jẹ́ ẹgbẹ̀fà ó lé mẹ́tàdínláàádọ́ta (1,247) 42Harimu jẹ́ ẹgbẹ̀rún ó lé mẹ́tàdínlógún (1,017). 43Àwọn ọmọ Lefi:
àwọn ọmọ
Jeṣua (láti ipasẹ̀ Kadmieli, láti ipasẹ̀ Hodafiah) jẹ́ mẹ́rìnléláàádọ́rin (74).
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.