Nehemiah 7:39
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn àlùfáà: àwọn ọmọ Jedaiah (láti ipasẹ̀ ìdílé Jeṣua) jẹ́ ogún dín lẹ́gbẹ̀rin ó dín méje (973)
Nehemiah 7:39 in English
Nehemiah 7:39 · Berean Standard Bible
The priests: the descendants of Jedaiah (through the house of Jeshua), 973;
Context
37Lodi, Hadidi, àti Ono jẹ́ ọ̀rìndínlẹ́gbẹ̀rin ó lé ọ̀kan (721) 38Senaa jẹ́ ẹgbàajì ó dín àádọ́rin (3,930). 39Àwọn àlùfáà:
àwọn ọmọ
Jedaiah (láti ipasẹ̀ ìdílé Jeṣua) jẹ́ ogún dín lẹ́gbẹ̀rin ó dín méje (973) 40Immeri jẹ́ àádọ́ta lé lẹ́gbẹ̀rún ó lé méjì (1,052) 41Paṣuri jẹ́ ẹgbẹ̀fà ó lé mẹ́tàdínláàádọ́ta (1,247)
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.