Native Bible

Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Senaa jẹ́ ẹgbàajì ó dín àádọ́rin (3,930).

Nehemiah 7:38 in English

Nehemiah 7:38 · Berean Standard Bible

and the descendants of Senaah, 3,930.

Context

36Jeriko jẹ́ ọ̀tàdínnírinwó ó lé márùn-ún (345). 37Lodi, Hadidi, àti Ono jẹ́ ọ̀rìndínlẹ́gbẹ̀rin ó lé ọ̀kan (721) 38Senaa jẹ́ ẹgbàajì ó dín àádọ́rin (3,930). 39Àwọn àlùfáà: àwọn ọmọ Jedaiah (láti ipasẹ̀ ìdílé Jeṣua) jẹ́ ogún dín lẹ́gbẹ̀rin ó dín méje (973) 40Immeri jẹ́ àádọ́ta lé lẹ́gbẹ̀rún ó lé méjì (1,052)

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.