Native Bible

Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Immeri jẹ́ àádọ́ta lé lẹ́gbẹ̀rún ó lé méjì (1,052)

Nehemiah 7:40 in English

Nehemiah 7:40 · Berean Standard Bible

the descendants of Immer, 1,052;

Context

38Senaa jẹ́ ẹgbàajì ó dín àádọ́rin (3,930). 39Àwọn àlùfáà: àwọn ọmọ Jedaiah (láti ipasẹ̀ ìdílé Jeṣua) jẹ́ ogún dín lẹ́gbẹ̀rin ó dín méje (973) 40Immeri jẹ́ àádọ́ta lé lẹ́gbẹ̀rún ó lé méjì (1,052) 41Paṣuri jẹ́ ẹgbẹ̀fà ó lé mẹ́tàdínláàádọ́ta (1,247) 42Harimu jẹ́ ẹgbẹ̀rún ó lé mẹ́tàdínlógún (1,017).

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.