Native Bible

Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Harimu jẹ́ ẹgbẹ̀rún ó lé mẹ́tàdínlógún (1,017).

Nehemiah 7:42 in English

Nehemiah 7:42 · Berean Standard Bible

and the descendants of Harim, 1,017.

Context

40Immeri jẹ́ àádọ́ta lé lẹ́gbẹ̀rún ó lé méjì (1,052) 41Paṣuri jẹ́ ẹgbẹ̀fà ó lé mẹ́tàdínláàádọ́ta (1,247) 42Harimu jẹ́ ẹgbẹ̀rún ó lé mẹ́tàdínlógún (1,017). 43Àwọn ọmọ Lefi: àwọn ọmọ Jeṣua (láti ipasẹ̀ Kadmieli, láti ipasẹ̀ Hodafiah) jẹ́ mẹ́rìnléláàádọ́rin (74). 44Àwọn akọrin: àwọn ọmọ Asafu jẹ́ méjìdínláàádọ́jọ (148).

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.