Nehemiah 7:43
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ọmọ Lefi: àwọn ọmọ Jeṣua (láti ipasẹ̀ Kadmieli, láti ipasẹ̀ Hodafiah) jẹ́ mẹ́rìnléláàádọ́rin (74).
Nehemiah 7:43 in English
Nehemiah 7:43 · Berean Standard Bible
The Levites: the descendants of Jeshua (through Kadmiel, through the line of Hodevah *), 74.
Context
41Paṣuri jẹ́ ẹgbẹ̀fà ó lé mẹ́tàdínláàádọ́ta (1,247) 42Harimu jẹ́ ẹgbẹ̀rún ó lé mẹ́tàdínlógún (1,017). 43Àwọn ọmọ Lefi:
àwọn ọmọ
Jeṣua (láti ipasẹ̀ Kadmieli, láti ipasẹ̀ Hodafiah) jẹ́ mẹ́rìnléláàádọ́rin (74). 44Àwọn akọrin:
àwọn ọmọ
Asafu jẹ́ méjìdínláàádọ́jọ (148). 45Àwọn aṣọ́nà:
àwọn ọmọ
Ṣallumu, Ateri, Talmoni,
Akkubu, Hatita, àti Ṣobai jẹ́ méjìdínlógóje (138).
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.