Native Bible

Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Lodi, Hadidi, àti Ono jẹ́ ọ̀rìndínlẹ́gbẹ̀rin ó lé ọ̀kan (721)

Nehemiah 7:37 in English

Nehemiah 7:37 · Berean Standard Bible

the men of Lod, Hadid, and Ono, 721;

Context

35Harimu jẹ́ ọ̀rìndínnírinwó (320) 36Jeriko jẹ́ ọ̀tàdínnírinwó ó lé márùn-ún (345). 37Lodi, Hadidi, àti Ono jẹ́ ọ̀rìndínlẹ́gbẹ̀rin ó lé ọ̀kan (721) 38Senaa jẹ́ ẹgbàajì ó dín àádọ́rin (3,930). 39Àwọn àlùfáà: àwọn ọmọ Jedaiah (láti ipasẹ̀ ìdílé Jeṣua) jẹ́ ogún dín lẹ́gbẹ̀rin ó dín méje (973)

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.