Native Bible

Lamentations 5:10 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ẹran-ara wa gbóná bí ààrò, ebi sì yó wa bí àárẹ̀.

Lamentations 5:10 in English

Lamentations 5:10 · Berean Standard Bible

Our skin is as hot as an oven with fever from our hunger.

Context

8Àwọn ẹrú ń jẹ ọba lórí wa, kò sì ṣí ẹni tí yóò gbà wá lọ́wọ́ wọn. 9Àwa ń rí oúnjẹ wa nínú ewu ẹ̀mí wa nítorí idà tí ó wà ní aginjù. 10Ẹran-ara wa gbóná bí ààrò, ebi sì yó wa bí àárẹ̀. 11Wọ́n ti fipá bá àwọn obìnrin wa lòpọ̀ ní Sioni, àti àwọn wúńdíá ti o wa ní ìlú Juda. 12Àwọn ọmọ ọbakùnrin ti di síso sókè ní ọwọ́ wọn; kò sí ìbọ̀wọ̀ fún àgbàgbà mọ́.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.