Native Bible

Lamentations 5:9 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwa ń rí oúnjẹ wa nínú ewu ẹ̀mí wa nítorí idà tí ó wà ní aginjù.

Lamentations 5:9 in English

Lamentations 5:9 · Berean Standard Bible

We get our bread at the risk of our lives because of the sword in the wilderness.

Context

7Àwọn baba wa ti ṣẹ̀, wọn kò sì ṣí mọ́, àwa sì ń ru ìjìyà ẹ̀ṣẹ̀ wọn. 8Àwọn ẹrú ń jẹ ọba lórí wa, kò sì ṣí ẹni tí yóò gbà wá lọ́wọ́ wọn. 9Àwa ń rí oúnjẹ wa nínú ewu ẹ̀mí wa nítorí idà tí ó wà ní aginjù. 10Ẹran-ara wa gbóná bí ààrò, ebi sì yó wa bí àárẹ̀. 11Wọ́n ti fipá bá àwọn obìnrin wa lòpọ̀ ní Sioni, àti àwọn wúńdíá ti o wa ní ìlú Juda.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.