Native Bible

Lamentations 5:8 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ẹrú ń jẹ ọba lórí wa, kò sì ṣí ẹni tí yóò gbà wá lọ́wọ́ wọn.

Lamentations 5:8 in English

Lamentations 5:8 · Berean Standard Bible

Slaves rule over us; there is no one to deliver us from their hands.

Context

6Àwa jọ̀wọ́ ara wa fún Ejibiti àti Asiria láti rí oúnjẹ tó tó jẹ. 7Àwọn baba wa ti ṣẹ̀, wọn kò sì ṣí mọ́, àwa sì ń ru ìjìyà ẹ̀ṣẹ̀ wọn. 8Àwọn ẹrú ń jẹ ọba lórí wa, kò sì ṣí ẹni tí yóò gbà wá lọ́wọ́ wọn. 9Àwa ń rí oúnjẹ wa nínú ewu ẹ̀mí wa nítorí idà tí ó wà ní aginjù. 10Ẹran-ara wa gbóná bí ààrò, ebi sì yó wa bí àárẹ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.