Ẹkún Jeremiah 5:11
Lamentations 5:11 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Wọ́n ti fipá bá àwọn obìnrin wa lòpọ̀ ní Sioni, àti àwọn wúńdíá ti o wa ní ìlú Juda.
Lamentations 5:11 in English
Lamentations 5:11 · Berean Standard Bible
Women have been ravished in Zion, virgins in the cities of Judah.
Context
9Àwa ń rí oúnjẹ wa nínú ewu ẹ̀mí wa
nítorí idà tí ó wà ní aginjù. 10Ẹran-ara wa gbóná bí ààrò,
ebi sì yó wa bí àárẹ̀. 11Wọ́n ti fipá bá àwọn obìnrin wa lòpọ̀ ní Sioni,
àti àwọn wúńdíá ti o wa ní ìlú Juda. 12Àwọn ọmọ ọbakùnrin ti di síso sókè ní ọwọ́ wọn;
kò sí ìbọ̀wọ̀ fún àgbàgbà mọ́. 13Àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin wa ru òkúta;
àwọn ọmọkùnrin sì ń ṣàárẹ̀ lábẹ́ ẹrù igi.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.