Native Bible

Lamentations 3:7 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ó ti tì mí mọ́ ilé, nítorí náà n kò le è sálọ; ó ti fi ẹ̀wọ̀n mú mi mọ́lẹ̀.

Lamentations 3:7 in English

Lamentations 3:7 · Berean Standard Bible

He has walled me in so I cannot escape; He has weighed me down with chains.

Context

5Ó ti fi mí sí ìgbèkùn, ó sì ti yí mi ká pẹ̀lú ìkorò àti làálàá. 6Ó mú mi gbé nínú òkùnkùn, bí ti àwọn tó ti kú fún ìgbà pípẹ́. 7Ó ti tì mí mọ́ ilé, nítorí náà n kò le è sálọ; ó ti fi ẹ̀wọ̀n mú mi mọ́lẹ̀. 8Pàápàá nígbà tí mo ké fún ìrànlọ́wọ́, ó kọ àdúrà mi. 9Ó fi ògiri òkúta dí ọ̀nà mi; ó sì mú ọ̀nà mi wọ́.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.