Native Bible

Lamentations 3:8 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Pàápàá nígbà tí mo ké fún ìrànlọ́wọ́, ó kọ àdúrà mi.

Lamentations 3:8 in English

Lamentations 3:8 · Berean Standard Bible

Even when I cry out and plead for help, He shuts out my prayer.

Context

6Ó mú mi gbé nínú òkùnkùn, bí ti àwọn tó ti kú fún ìgbà pípẹ́. 7Ó ti tì mí mọ́ ilé, nítorí náà n kò le è sálọ; ó ti fi ẹ̀wọ̀n mú mi mọ́lẹ̀. 8Pàápàá nígbà tí mo ké fún ìrànlọ́wọ́, ó kọ àdúrà mi. 9Ó fi ògiri òkúta dí ọ̀nà mi; ó sì mú ọ̀nà mi wọ́. 10Bí i beari tí ó dùbúlẹ̀, bí i kìnnìún tí ó sá pamọ́.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.