Native Bible

Lamentations 3:9 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ó fi ògiri òkúta dí ọ̀nà mi; ó sì mú ọ̀nà mi wọ́.

Lamentations 3:9 in English

Lamentations 3:9 · Berean Standard Bible

He has barred my ways with cut stones; He has made my paths crooked.

Context

7Ó ti tì mí mọ́ ilé, nítorí náà n kò le è sálọ; ó ti fi ẹ̀wọ̀n mú mi mọ́lẹ̀. 8Pàápàá nígbà tí mo ké fún ìrànlọ́wọ́, ó kọ àdúrà mi. 9Ó fi ògiri òkúta dí ọ̀nà mi; ó sì mú ọ̀nà mi wọ́. 10Bí i beari tí ó dùbúlẹ̀, bí i kìnnìún tí ó sá pamọ́. 11Ó wọ́ mi kúrò ní ọ̀nà, ó tẹ̀ mí mọ́lẹ̀ ó fi mi sílẹ̀ láìsí ìrànlọ́wọ́.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.