Ẹkún Jeremiah 3:6
Lamentations 3:6 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ó mú mi gbé nínú òkùnkùn, bí ti àwọn tó ti kú fún ìgbà pípẹ́.
Lamentations 3:6 in English
Lamentations 3:6 · Berean Standard Bible
He has made me dwell in darkness like those dead for ages.
Context
4Ó jẹ́ kí àwọ̀ mi àti ẹran-ara mi gbó
ó sì tún ṣẹ́ egungun mi. 5Ó ti fi mí sí ìgbèkùn, ó sì ti yí mi ká
pẹ̀lú ìkorò àti làálàá. 6Ó mú mi gbé nínú òkùnkùn,
bí ti àwọn tó ti kú fún ìgbà pípẹ́. 7Ó ti tì mí mọ́ ilé, nítorí náà n kò le è sálọ;
ó ti fi ẹ̀wọ̀n mú mi mọ́lẹ̀. 8Pàápàá nígbà tí mo ké fún ìrànlọ́wọ́,
ó kọ àdúrà mi.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.