Jobu 15:3
Job 15:3 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Òun lè máa fi àròyé sọ̀rọ̀ tí kò ní èrè, tàbí pẹ̀lú ọ̀rọ̀ nínú èyí tí kò lè fi ṣe rere?
Job 15:3 in English
Job 15:3 · Berean Standard Bible
Should he argue with useless words or speeches that serve no purpose?
Context
1Ìgbà náà ní Elifasi, ará Temani, dáhùn wí pé, 2“Ọlọ́gbọ́n a máa sọ̀rọ̀ ìmọ̀ asán
kí ó sì máa fi afẹ́fẹ́ ìlà-oòrùn kún ara rẹ̀ nínú? 3Òun lè máa fi àròyé sọ̀rọ̀ tí kò ní èrè,
tàbí pẹ̀lú ọ̀rọ̀ nínú èyí tí kò lè fi ṣe rere? 4Ṣùgbọ́n ìwọ ṣá ìbẹ̀rù tì,
ìwọ sì dí iṣẹ́ ìsìn lọ́nà níwájú Ọlọ́run. 5Nítorí pé ẹnu ara rẹ̀ ni ó jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀,
ìwọ sì yàn ahọ́n alárékérekè ni ààyò.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.