Native Bible

Job 15:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ìgbà náà ní Elifasi, ará Temani, dáhùn wí pé,

Job 15:1 in English

Job 15:1 · Berean Standard Bible

Then Eliphaz the Temanite replied:

Context

1Ìgbà náà ní Elifasi, ará Temani, dáhùn wí pé, 2“Ọlọ́gbọ́n a máa sọ̀rọ̀ ìmọ̀ asán kí ó sì máa fi afẹ́fẹ́ ìlà-oòrùn kún ara rẹ̀ nínú? 3Òun lè máa fi àròyé sọ̀rọ̀ tí kò ní èrè, tàbí pẹ̀lú ọ̀rọ̀ nínú èyí tí kò lè fi ṣe rere?

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.