Jobu 15:5
Job 15:5 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nítorí pé ẹnu ara rẹ̀ ni ó jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, ìwọ sì yàn ahọ́n alárékérekè ni ààyò.
Job 15:5 in English
Job 15:5 · Berean Standard Bible
For your iniquity instructs your mouth, and you choose the language of the crafty.
Context
3Òun lè máa fi àròyé sọ̀rọ̀ tí kò ní èrè,
tàbí pẹ̀lú ọ̀rọ̀ nínú èyí tí kò lè fi ṣe rere? 4Ṣùgbọ́n ìwọ ṣá ìbẹ̀rù tì,
ìwọ sì dí iṣẹ́ ìsìn lọ́nà níwájú Ọlọ́run. 5Nítorí pé ẹnu ara rẹ̀ ni ó jẹ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀,
ìwọ sì yàn ahọ́n alárékérekè ni ààyò. 6Ẹnu ara rẹ̀ ni ó dá lẹ́bi, kì í ṣe èmi;
àní ètè ara rẹ̀ ni ó jẹ́rìí gbè ọ́. 7“Ìwọ ha í ṣe ọkùnrin tí a kọ́ bí?
Tàbí a ha dá ọ ṣáájú àwọn òkè?
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.