Native Bible

Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

sórí Kerioti àti Bosra, sórí gbogbo ìlú Moabu, nítòsí àti ní ọ̀nà jíjìn.

Jeremiah 48:24 in English

Jeremiah 48:24 · Berean Standard Bible

upon Kerioth, Bozrah, and all the towns of Moab, those far and near.

Context

22sórí Diboni, Nebo àti Beti-Diblataimu, 23sórí Kiriataimu, Beti-Gamu àti Beti-Meoni, 24sórí Kerioti àti Bosra, sórí gbogbo ìlú Moabu, nítòsí àti ní ọ̀nà jíjìn. 25A gé ìwo Moabu kúrò, apá rẹ̀ dá,” ni Olúwa wí. 26“Ẹ jẹ́ kí a mú u mutí nítorí ó kó ìdọ̀tí bá Olúwa, jẹ́ kí Moabu lúwẹ̀ẹ́ nínú èébì rẹ̀, kí ó di ẹni ẹ̀gàn.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.