Jeremiah 48:22
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
sórí Diboni, Nebo àti Beti-Diblataimu,
Jeremiah 48:22 in English
Jeremiah 48:22 · Berean Standard Bible
upon Dibon, Nebo, and Beth-diblathaim,
Context
20Ojú ti Moabu nítorí tí a wó o lulẹ̀.
Ẹ hu, kí ẹ sì kígbe!
Ẹ kéde rẹ̀ ní Arnoni pé,
a pa Moabu run. 21Ìdájọ́ ti dé sí àwọn òkè pẹrẹsẹ,
sórí Holoni, Jahisa àti Mefaati, 22sórí Diboni, Nebo àti Beti-Diblataimu, 23sórí Kiriataimu, Beti-Gamu àti Beti-Meoni, 24sórí Kerioti àti Bosra,
sórí gbogbo ìlú Moabu, nítòsí àti ní ọ̀nà jíjìn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.