Native Bible

Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

A gé ìwo Moabu kúrò, apá rẹ̀ dá,” ni Olúwa wí.

Jeremiah 48:25 in English

Jeremiah 48:25 · Berean Standard Bible

The horn of Moab has been cut off, and his arm is broken,” declares the LORD.

Context

23sórí Kiriataimu, Beti-Gamu àti Beti-Meoni, 24sórí Kerioti àti Bosra, sórí gbogbo ìlú Moabu, nítòsí àti ní ọ̀nà jíjìn. 25A gé ìwo Moabu kúrò, apá rẹ̀ dá,” ni Olúwa wí. 26“Ẹ jẹ́ kí a mú u mutí nítorí ó kó ìdọ̀tí bá Olúwa, jẹ́ kí Moabu lúwẹ̀ẹ́ nínú èébì rẹ̀, kí ó di ẹni ẹ̀gàn. 27Ǹjẹ́ Israẹli kò di ẹni ẹ̀gàn rẹ? Ǹjẹ́ a kó o pẹ̀lú àwọn olè tó bẹ́ẹ̀ tí o ń gbọn orí rẹ̀ pẹ̀lú yẹ̀yẹ́ nígbàkígbà bí a bá sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀?

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.