Jeremiah 25:23
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Dedani, Tema, Busi àti gbogbo àwọn tí ń gbé lọ́nà jíjìn réré.
Jeremiah 25:23 in English
Jeremiah 25:23 · Berean Standard Bible
Dedan, Tema, Buz, and all who cut the corners of their hair;
Context
21Edomu, Moabu àti Ammoni; 22gbogbo àwọn ọba Tire àti Sidoni;
gbogbo àwọn ọba erékùṣù wọ̀n-ọn-nì tí ń bẹ ní ìkọjá Òkun. 23Dedani, Tema, Busi àti gbogbo àwọn tí ń gbé lọ́nà jíjìn réré. 24Gbogbo àwọn ọba Arabia àti àwọn ọba àwọn àjèjì ènìyàn tí ń gbé inú aginjù. 25Gbogbo àwọn ọba Simri, Elamu àti Media.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.