Native Bible

Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

gbogbo àwọn ọba Tire àti Sidoni; gbogbo àwọn ọba erékùṣù wọ̀n-ọn-nì tí ń bẹ ní ìkọjá Òkun.

Jeremiah 25:22 in English

Jeremiah 25:22 · Berean Standard Bible

all the kings of Tyre and Sidon; the kings of the coastlands across the sea;

Context

20Àti gbogbo àwọn ènìyàn àjèjì tí ó wà níbẹ̀; gbogbo àwọn ọba Usi, gbogbo àwọn ọba Filistini, gbogbo àwọn ti Aṣkeloni, Gasa, Ekroni àti gbogbo àwọn ènìyàn tí ó kù sí Aṣdodu. 21Edomu, Moabu àti Ammoni; 22gbogbo àwọn ọba Tire àti Sidoni; gbogbo àwọn ọba erékùṣù wọ̀n-ọn-nì tí ń bẹ ní ìkọjá Òkun. 23Dedani, Tema, Busi àti gbogbo àwọn tí ń gbé lọ́nà jíjìn réré. 24Gbogbo àwọn ọba Arabia àti àwọn ọba àwọn àjèjì ènìyàn tí ń gbé inú aginjù.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.