Jeremiah 25:21
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Edomu, Moabu àti Ammoni;
Jeremiah 25:21 in English
Jeremiah 25:21 · Berean Standard Bible
Edom, Moab, and the Ammonites;
Context
19Farao ọba Ejibiti, àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀, àwọn aláṣẹ rẹ̀ àti àwọn ènìyàn rẹ̀. 20Àti gbogbo àwọn ènìyàn àjèjì tí ó wà níbẹ̀;
gbogbo àwọn ọba Usi,
gbogbo àwọn ọba Filistini, gbogbo àwọn ti Aṣkeloni, Gasa, Ekroni àti gbogbo àwọn ènìyàn tí ó kù sí Aṣdodu. 21Edomu, Moabu àti Ammoni; 22gbogbo àwọn ọba Tire àti Sidoni;
gbogbo àwọn ọba erékùṣù wọ̀n-ọn-nì tí ń bẹ ní ìkọjá Òkun. 23Dedani, Tema, Busi àti gbogbo àwọn tí ń gbé lọ́nà jíjìn réré.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.