Jeremiah 25:24
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Gbogbo àwọn ọba Arabia àti àwọn ọba àwọn àjèjì ènìyàn tí ń gbé inú aginjù.
Jeremiah 25:24 in English
Jeremiah 25:24 · Berean Standard Bible
all the kings of Arabia, and all the kings of the mixed tribes who dwell in the desert;
Context
22gbogbo àwọn ọba Tire àti Sidoni;
gbogbo àwọn ọba erékùṣù wọ̀n-ọn-nì tí ń bẹ ní ìkọjá Òkun. 23Dedani, Tema, Busi àti gbogbo àwọn tí ń gbé lọ́nà jíjìn réré. 24Gbogbo àwọn ọba Arabia àti àwọn ọba àwọn àjèjì ènìyàn tí ń gbé inú aginjù. 25Gbogbo àwọn ọba Simri, Elamu àti Media. 26Àti gbogbo àwọn ọba àríwá ní tòsí àti lọ́nà jíjìn, ẹnìkínní lẹ́yìn ẹnìkejì; gbogbo àwọn ìjọba lórí orílẹ̀ ayé.
Àti gbogbo wọn, ọba Ṣeṣaki náà yóò sì mu.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.