Onidajọ 5:20
Judges 5:20 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ìràwọ̀ já láti ojú ọ̀run wá láti inú ipa ọ̀nà wọn ni wọ́n bá Sisera jà.
Judges 5:20 in English
Judges 5:20 · Berean Standard Bible
From the heavens the stars fought; from their courses they fought against Sisera.
Context
18Àwọn ènìyàn Sebuluni fi ẹ̀mí wọn wéwu ikú;
bẹ́ẹ̀ sì ni àwọn ènìyàn Naftali ní ibi gíga pápá. 19“Àwọn ọba wá, wọ́n sì jà;
àwọn ọba Kenaani jà
ní Taanaki ní etí odo Megido,
ṣùgbọ́n wọn kò sì gba èrè owó. 20Àwọn ìràwọ̀ já láti ojú ọ̀run wá
láti inú ipa ọ̀nà wọn ni wọ́n bá Sisera jà. 21Odò Kiṣoni gbá wọn lọ,
odò ìgbàanì, odò Kiṣoni.
Máa yan lọ, ìwọ ọkàn mi, nínú agbára! 22Nígbà náà ni pátákò ẹsẹ̀ ẹṣin ki ilẹ̀,
nítorí eré sísá, eré sísá àwọn alágbára wọn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.