Gẹnẹsisi 49:20
Genesis 49:20 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
“Oúnjẹ Aṣeri yóò dára; yóò ṣe àsè tí ó yẹ fún ọba.
Genesis 49:20 in English
Genesis 49:20 · Berean Standard Bible
Asher’s food will be rich; he shall provide royal delicacies.
Context
18“Mo ń dúró de ìtúsílẹ̀ rẹ, Olúwa. 19“Ẹgbẹ́ ogun àwọn ẹlẹ́ṣin yóò kọlu Gadi,
ṣùgbọ́n yóò kọlu wọ́n ní gìgísẹ̀ wọn. 20“Oúnjẹ Aṣeri yóò dára;
yóò ṣe àsè tí ó yẹ fún ọba. 21“Naftali yóò jẹ́ abo àgbọ̀nrín
tí a tú sílẹ̀ tí ó ń bí ọmọ dáradára. 22“Josẹfu jẹ́ àjàrà eléso,
àjàrà eléso ní etí odò,
tí ẹ̀ka rẹ̀ gun orí odi.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.