Gẹnẹsisi 49:19
Genesis 49:19 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
“Ẹgbẹ́ ogun àwọn ẹlẹ́ṣin yóò kọlu Gadi, ṣùgbọ́n yóò kọlu wọ́n ní gìgísẹ̀ wọn.
Genesis 49:19 in English
Genesis 49:19 · Berean Standard Bible
Gad * will be attacked by raiders, but he will attack their heels.
Context
17Dani yóò jẹ́ ejò ni pópónà
àti paramọ́lẹ̀ ní ẹ̀bá ọ̀nà,
tí ó bu ẹṣin jẹ ní ẹsẹ̀,
kí ẹni tí ń gùn ún bá à le è ṣubú sẹ́yìn. 18“Mo ń dúró de ìtúsílẹ̀ rẹ, Olúwa. 19“Ẹgbẹ́ ogun àwọn ẹlẹ́ṣin yóò kọlu Gadi,
ṣùgbọ́n yóò kọlu wọ́n ní gìgísẹ̀ wọn. 20“Oúnjẹ Aṣeri yóò dára;
yóò ṣe àsè tí ó yẹ fún ọba. 21“Naftali yóò jẹ́ abo àgbọ̀nrín
tí a tú sílẹ̀ tí ó ń bí ọmọ dáradára.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.