Native Bible

Genesis 49:18 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

“Mo ń dúró de ìtúsílẹ̀ rẹ, Olúwa.

Genesis 49:18 in English

Genesis 49:18 · Berean Standard Bible

I await Your salvation, O LORD.

Context

16“Dani yóò ṣe ìdájọ́ àwọn ènìyàn rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ọ̀kan nínú àwọn ẹ̀yà Israẹli. 17Dani yóò jẹ́ ejò ni pópónà àti paramọ́lẹ̀ ní ẹ̀bá ọ̀nà, tí ó bu ẹṣin jẹ ní ẹsẹ̀, kí ẹni tí ń gùn ún bá à le è ṣubú sẹ́yìn. 18“Mo ń dúró de ìtúsílẹ̀ rẹ, Olúwa. 19“Ẹgbẹ́ ogun àwọn ẹlẹ́ṣin yóò kọlu Gadi, ṣùgbọ́n yóò kọlu wọ́n ní gìgísẹ̀ wọn. 20“Oúnjẹ Aṣeri yóò dára; yóò ṣe àsè tí ó yẹ fún ọba.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.