Gẹnẹsisi 46:23
Genesis 46:23 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ọmọ Dani: Huṣimu.
Genesis 46:23 in English
Genesis 46:23 · Berean Standard Bible
The son of Dan: Hushim.
Context
21Àwọn ọmọ Benjamini:
Bela, Bekeri, Aṣbeli, Gera, Naamani, Ehi, Roṣi, Mupimu, Huppimu àti Ardi. 22Wọ̀nyí ni àwọn ọmọkùnrin tí Rakeli bí fún Jakọbu. Wọ́n jẹ́ mẹ́rìnlá lápapọ̀. 23Àwọn ọmọ Dani:
Huṣimu. 24Àwọn ọmọ Naftali:
Jasieli, Guni, Jeseri, àti Ṣillemu. 25Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ tí Biliha ẹni tí Labani fi fún Rakeli ọmọ rẹ̀ bí fún Jakọbu. Wọ́n jẹ́ méje lápapọ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.