Gẹnẹsisi 46:24
Genesis 46:24 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ọmọ Naftali: Jasieli, Guni, Jeseri, àti Ṣillemu.
Genesis 46:24 in English
Genesis 46:24 · Berean Standard Bible
The sons of Naphtali: Jahzeel, Guni, Jezer, and Shillem.
Context
22Wọ̀nyí ni àwọn ọmọkùnrin tí Rakeli bí fún Jakọbu. Wọ́n jẹ́ mẹ́rìnlá lápapọ̀. 23Àwọn ọmọ Dani:
Huṣimu. 24Àwọn ọmọ Naftali:
Jasieli, Guni, Jeseri, àti Ṣillemu. 25Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ tí Biliha ẹni tí Labani fi fún Rakeli ọmọ rẹ̀ bí fún Jakọbu. Wọ́n jẹ́ méje lápapọ̀. 26Gbogbo àwọn tí ó lọ pẹ̀lú Jakọbu sí Ejibiti, àwọn tí ó jẹ́ ìran rẹ̀ tààrà láìka àwọn aya ọmọ rẹ̀, jẹ́ ènìyàn mẹ́rìndínláàádọ́rin.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.