Gẹnẹsisi 46:22
Genesis 46:22 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Wọ̀nyí ni àwọn ọmọkùnrin tí Rakeli bí fún Jakọbu. Wọ́n jẹ́ mẹ́rìnlá lápapọ̀.
Genesis 46:22 in English
Genesis 46:22 · Berean Standard Bible
These are the sons of Rachel born to Jacob—fourteen in all.
Context
20Ní Ejibiti, Asenati ọmọbìnrin Potifẹra, alábojútó àti àlùfáà Oni, bí Manase àti Efraimu fún Josẹfu. 21Àwọn ọmọ Benjamini:
Bela, Bekeri, Aṣbeli, Gera, Naamani, Ehi, Roṣi, Mupimu, Huppimu àti Ardi. 22Wọ̀nyí ni àwọn ọmọkùnrin tí Rakeli bí fún Jakọbu. Wọ́n jẹ́ mẹ́rìnlá lápapọ̀. 23Àwọn ọmọ Dani:
Huṣimu. 24Àwọn ọmọ Naftali:
Jasieli, Guni, Jeseri, àti Ṣillemu.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.